ÀDÚRÀ AIYÉ TITUN

200.00

Ọ̀nà Bẹtlẹhẹmu ti Judea kò ba mi lẹrù ni ọjọ ti mo gbọ wípé a bi Olugbala, o bọ ogo rẹ silẹ̀, o gbe wọ mi, mo wólẹ̀ niwaju rẹ, mo gba ọla, mo gba aikú, mo ti ba Noa sọ̀kalẹ̀ ninu ọkọ̀, mi o ba omi lọ, isinmi de, aiyé titun bẹ̀rẹ̀……

Goṣeni kò bajẹ laiyé Josefu, Jẹriko kò bajẹ laiyé Joṣua, Kenaani ko bajẹ laiyé ọmọ Israẹli, Nigeria kò ni bajẹ ni aiyé temi…

Ori ti a ṣà ni ilẹ́ to ṣá ni Ijéṣà ni Woli Ayọ bu iyọ si ni ilẹ̀ ti a ṣà, omi di omi Ayọ̀, iletò di ileṣa, aṣeyọri bẹ̀rẹ̀…

Baba mi kò lè ta ẹ̀jẹ̀ silẹ, iya mi lo ta ẹ̀jẹ̀ silẹ̀, ki o to bi mi si aiyé ṣugbọn ẹ̀jẹ̀ Jesu lo sọ aiyé mi di titun… NOTE: You will need to download an E-book reader on your mobile device before you can access the book.

Additional information

NOTE

NOTE: You will need to download an E-book reader on your mobile device before you can access the book.

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “ÀDÚRÀ AIYÉ TITUN”

Your email address will not be published. Required fields are marked *