ÀDÚRÀ FÚN IGBEGA
₦200.00
Ẹlomiran kò gbudọ jẹ ọba ni ilé Jesse lẹhin Dafidi, ki ọmọ mi di ọba ni idile mi ati ni ayé loni…
Ori Jakọbu, ori ùre, ki baba súre fun, ki ìyá súre fun, ki Labani súre fun, ki Angẹli súre fun, ki Seraphim alaṣọ funfun máa ṣe iranṣẹ fun ọmọ mi ninu aiyé…
Ati ibi ati ire mi ki Oluwa fi wọn pamọ fun ọta ki wọn máa ri, bi wọn ba ri ibi wọn yoo fikun, bi wọn ba ri ire, wọn yóò bájẹ.
Ẹyẹ mẹta, ẹyẹ ire, Ẹyẹ Idì, gbe mi de ibi ire;Ẹyẹ Iwò, gbere pade mi ni aginju ayé; Ẹyẹ Adaba, fi ọkan mi balẹ…
wọn le mi jade ninu ọgbà Edẹni, wọn gba mi wọ ilé ninu ọgbà Gẹtsemani, wọn pe mi lẹjọ laarin òkunkun, Olugbala dami lare lori oke Kalfari, Ó gba mi lọ́wọ́ ọ̀tá mi tí ó lágbára ati lọ́wọ́ awọn tí ó kórìíra mi;
Reviews
There are no reviews yet.