Sale!

ÀDÚRÀ SỌ ÒKÚ DI ALÀÀYÈ

200.00

Gbè mí ni ìjà, gbè jà mi jà, jà fun mi, já àjàgà mi kuro, kájà gbe mi gun òkè nitori Elijah ni mo jẹ́. ..

Mo tẹle Mose, okun pinya, mo tẹle Joṣua, Jordani pinyà, mo tẹle Jesu, Eṣu ti yago loju ọ̀nà mi, ìkorò mi di didùn, mo bu iyọ si orisun, aṣálẹ̀ mi di ilẹ̀ ọlọra….

Mo ti gbọ ohun Oluwa ni sàárè, mo tají, tu mi silẹ ki n máa lọ, aṣọ ikú bọ́, ẹrù ẹ̀ṣẹ̀ bọ́, mo bọ lọwọ ayé, ija dopin…..

ikú ti di èèwọ mi, ọmọ mẹta, ijoye mejila, ikú kan kò gbudọ pa mi, mo di ọba, ewé gbẹ, egbò gbẹ, mo ti gbe àkéte mi, ikú ti re mi kété…. NOTE: You will need to download an E-book reader on your mobile device before you can access the book.

Category:

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “ÀDÚRÀ SỌ ÒKÚ DI ALÀÀYÈ”

Your email address will not be published. Required fields are marked *