Sale!
Ẹ̀RU NI ỌLỌRUN
₦200.00
Emi ni ọmọ ìmọ́lẹ̀ ti on la iná kọjá, Ogun-Ọrun fi iná dán mi wò, mo yọ bi wura…
N ó ni ba wọn mu omi ipọnju, asiko to ti n ó ṣe ikore ninú ayé, ki ibukun ati ọrọ̀ awọn keferi máa jẹ temi…
Ìlú ni mi ti a fi wura mọ, pẹlu okuta-iyebiye ni Ogun-Ọrun fi ṣe ipilẹ̀ mi, ìmọ́lẹ̀ mi kii ṣe ti NEPA, ọdọ-agutan ni ìmọ́lẹ̀ mi…
Mo ti di ajitan-na-wo, ijọba ibukun bọ si mi lọwọ́, ọ̀tá mi di ẹni ikogun, ọ̀tá mi di ẹrù olè… NOTE: You will need to download an E-book reader on your mobile device before you can access the book.
Reviews
There are no reviews yet.