Sale!
ỌFA ALAGBARA
₦300.00
Kò si ẹniti kò ni lọ si ori agbelebu ninu gbogbo awọn ọmọ lẹhin Kristi ki wọn to le lọ si ọrun rere, bi tirẹ̀ kò ba i de loni, o ń bọ lọna, èyi ni idanwò ìgbàgbọ́ yin ti o le mu ẹ gbà ade ologo
Bi ọmọ Ọlọrun otitọ ba wa ninu iṣoro kan tàbi ibanujẹ, ohun ti Ọlọrun fẹ ki ẹni náa ṣe ni wipe ki o yẹ iṣẹ rẹ wo, ki o si ronu gbogbo aṣiṣe rẹ, ibiti o ti ṣubu ki o si ṣe atunṣe.
kò si ẹniti kò ni ri idanwò tirẹ̀ yàlá nipa ẹ̀ṣẹ tàbi nipa ihinrere ti o gba, idanwò wa niwaju rẹ, agbelebu onikaluku wa ni ejika rẹ ṣugbọn máa tẹle Jesu iwọ yóò di aṣẹgun.
Reviews
There are no reviews yet.