Sale!

ỌMỌ NÁÀ KÒ KÚ

200.00

Bi o ba gba Jesu gbọ tọkantọkan, akoko kan yóò wa ninu ayé rẹ ti awọn ènìyàn yóò fi o máa rẹrin ti wọn yóò máa ṣe ẹlẹya rẹ, wọn yóò sọ wipe omi ti tan lẹhin ẹja rẹ…

Kò si nkan ti o bajẹ tan ni ọ̀dọ̀ ènìyàn ti Jesu kò le tunṣe bi ẹyin ènìyàn ba ni suuru pẹlu igbàgbọ́…

Kò si iṣẹ Èṣu ninu ayé ẹyin ọmọ ènìyàn ti o le da iṣẹ́ Ọlọrun duro, kaka bẹẹ, imọlẹ náà yóò máa mọlẹ láàrin òkunkun, òkunkun kan kò si le bori rẹ…

Iṣẹ́ iyanu Ọlọrun ki iṣe ti faari tabi ṣe karimi tabi ti awọn alupayida tabi ti afọṣẹ ṣugbọn fun ògo Ọlọrun…

Nigbati ènìyàn buburu ba ń ṣe idena àdúrà iṣẹ́ Ọlọrun, kì í ṣe wipe Ọlọrun jẹ Ọlọrun okú, ohun meji ni Ọlọrun fẹ ki ènìyàn mọ, ikini ni ìrònúpìwàdà, ikeji ògo-Ọlọrun…NOTE: You will need to download an E-book reader on your mobile device before you can access the book.

Category:

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “ỌMỌ NÁÀ KÒ KÚ”

Your email address will not be published. Required fields are marked *